Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

A6-B

Àtẹ: Àwọn Wòlíì àti Àwọn Ọba Ilẹ̀ Júdà àti Ísírẹ́lì (Apá Kejì)

Àwọn Ọba Ìjọba Gúúsù (A ti ń bá a bọ̀)

777 Ṣ.S.K.

Jótámù: 16 ọdún

762

Áhásì: 16 ọdún

746

Hẹsikáyà: 29 ọdún

716

Mánásè: 55 ọdún

661

Ámọ́nì: 2 ọdún

659

Jòsáyà: 31 ọdún

628

Jèhóáhásì: oṣù 3

Jèhóákímù: 11 ọdún

618

Jèhóákínì: oṣù 3, ọjọ́ 10

617

Sedekáyà: 11 ọdún

607

Nebukadinésárì ọba Bábílónì àtàwọn èèyàn rẹ̀ ṣígun wá, wọ́n sì pa Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì run. Wọ́n mú Sedekáyà, ọba ìlà ìdílé Dáfídì tó jẹ kẹ́yìn ní ayé kúrò lórí ìtẹ́

Àwọn Ọba Ìjọba Àríwá (A ti ń bá a bọ̀)

n. 803 B.C.E.

Sekaráyà: àkọsílẹ̀ fi hàn pé oṣù 6 péré lo fi jọba

Sekaráyà bẹ̀rẹ̀ sí í jọba lọ́nà kan ṣáá, àmọ́ ẹ̀rí fi hàn pé nǹkan bí ọdún 792 ni ìjọba náà tó di tirẹ̀

n. 791

Ṣálúmù: oṣù 1

Ménáhémù: 10 ọdún

n. 780

Pekaháyà: 2 ọdún

n. 778

Pékà: 20 ọdún

n. 758

Hóṣéà: 9 ọdún láti n. 748

n. 748

Ó jọ pé ìṣàkóso Hóṣéà wá fìdí múlẹ̀ dáadáa tàbí pé ó rí ìtìlẹ́yìn gbà látọ̀dọ̀ ọba Ásíríà, Tigilati-pílésà Kẹta ní nǹkan bí ọdún 748

740

Ásíríà ṣẹ́gun Samáríà, ó tẹ Ísírẹ́lì lórí ba; ìjọba ẹ̀yà mẹ́wàá àríwá Ísírẹ́lì dópin

 • Orúkọ Àwọn Wòlíì

 • Àìsáyà

 • Míkà

 • Sefanáyà

 • Jeremáyà

 • Náhúmù

 • Hábákúkù

 • Dáníẹ́lì

 • Ìsíkíẹ́lì

 • Ọbadáyà

 • Hósíà