Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

A7-E

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tó Ta Yọ Tí Jésù Ṣe ní Gálílì (Apá Kejì)

ÀKÓKÒ

IBI

ÌṢẸ̀LẸ̀

MÁTÍÙ

MÁÀKÙ

LÚÙKÙ

JÒHÁNÙ

31 tàbí 32

Agbègbè Kápánáúmù

Jésù ṣe àpèjúwe nípa Ìjọba Ọlọ́run

13:1-53

4:1-34

8:4-18

 

Òkun Gálílì

Ó dá ìjì dúró nígbà tó wà nínú ọkọ̀ ojú omi

8:18, 23-27

4:35-41

8:22-25

 

Agbègbè Gádárà

Ó lé àwọn ẹ̀mí èṣù sínú àwọn ẹlẹ́dẹ̀

8:28-34

5:1-20

8:26-39

 

Ó lè jẹ́ ní Kápánáúmù

Ó wo obìnrin tó ní ìsun ẹ̀jẹ̀ sàn; ó jí ọmọbìnrin Jáírù dìde

9:18-26

5:21-43

8:40-56

 

Kápánáúmù (?)

Ó ṣe ìwòsàn fún afọ́jú àti ẹni tí kò lè sọ̀rọ̀

9:27-34

     

Násárẹ́tì

Àwọn ará ìlú rẹ̀ tún kọ̀ ọ́

13:54-58

6:1-5

   

Gálílì

Ìrìn àjò rẹ̀ kẹta ní Gálílì; ó mú iṣẹ́ rẹ̀ gbòòrò sí i nígbà tó rán àwọn àpọ́sítélì jáde

9:35–11:1

6:6-13

9:1-6

 

Tìbéríà

Tìbéríà Hẹ́rọ́dù bẹ́ Jòhánù Arinibọmi lórí; Ọ̀rọ̀ nípa Jésù rú Hẹ́rọ́dù lójú

14:1-12

6:14-29

9:7-9

 

32, Ìrékọjá sún mọ́lé (Jo 6:4)

Kápánáúmù (?); Àríwá Ìlà Oòrùn Òkun Gálílì

Àwọn àpọ́sítélì dé láti ìrìn àjò iṣẹ́ ìwàásù; Jésù bọ́ 5,000 ọkùnrin

14:13-21

6:30-44

9:10-17

6:1-13

Àríwá Ìlà Oòrùn Òkun Gálílì; Jẹ́nẹ́sárẹ́tì

Àwọn èèyàn fẹ́ fi Jésù jọba; ó rìn lórí òkun; ó wo ọ̀pọ̀lọpọ̀ sàn

14:22-36

6:45-56

 

6:14-21

Kápánáúmù

Ó sọ pé òun ni “oúnjẹ ìyè”; ọ̀pọ̀ kọsẹ̀, wọ́n sì lọ

     

6:22-71

32, lẹ́yìn Ìrékọjá

Ó lè jẹ́ ní Kápánáúmù

Ó bẹnu àtẹ́ lu àṣà àtọwọ́dọ́wọ́

15:1-20

7:1-23

 

7:1

Foníṣíà; Dekapólì

Ó wo ọmọ obìnrin ará Foníṣíà ti Síríà sàn; ó bọ́ 4,000 ọkùnrin

15:21-38

7:24–8:9

   

Mágádánì

Àmì Jónà nìkan ló fún àwọn èèyàn

15:39–16:4

8:10-12