Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

 B12-A

Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kìíní)

Nísàn 8 (Sábáàtì)

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀, ó sì máa ń parí sí ìgbà tí oòrùn bá wọ̀)

 • Ó dé sí Bẹ́tánì lọ́jọ́ mẹ́fà ṣáájú ọjọ́ Ìrékọjá

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

 Nísàn 9

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

 • Ó bá Símónì adẹ́tẹ̀ jẹun

 • Màríà da òróró náádì sí Jésù lórí

 • Àwọn Júù wá wo Jésù àti Lásárù

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

 • Ó wọ Jerúsálẹ́mù tiyì-tẹ̀yẹ

 • Ó kọ́ni ní tẹ́ńpìlì

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

Nísàn 10

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

 • Ó sun Bẹ́tánì mọ́jú

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

 • Ìrìn àjò ní kùtùkùtù sí Jerúsálẹ́mù

 • Ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́

 • Jèhófà sọ̀rọ̀ látọ̀run

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

Nísàn 11

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

 • Ó kọ́ni ní tẹ́ńpìlì, ó lo àpèjúwe

 • Ó dẹ́bi fún àwọn Farisí

 • Ó kíyè sí ọrẹ tí opó kan ṣe

 • Lórí Òkè Ólífì, ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ ìparun Jerúsálẹ́mù àti àmì ìgbà tó máa wà níhìn-ín

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀