Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

A7-F

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Tún Ṣe ní Ìlà Oòrùn Jọ́dánì

ÀKÓKÒ

IBI

ÌṢẸ̀LẸ̀

MÁTÍÙ

MÁÀKÙ

LÚÙKÙ

JÒHÁNÙ

32, lẹ́yìn Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́

Bẹ́tánì ní òdìkejì

Jọ́dánì Ó lọ síbi tí Jòhánù ti ń ṣèrìbọmi fún àwọn èèyàn; ọ̀pọ̀ gba Jésù gbọ́

     

10:40-42

Pèríà

Ó rọ àwọn èèyàn pé kí wọ́n gba ẹnu ọ̀nà tóóró wọlé; ó kédàárò lórí Jerúsálẹ́mù

   

13:22

 

Ó rọ àwọn èèyàn pé kí wọ́n gba ẹnu ọ̀nà tóóró wọlé; ó kédàárò lórí Jerúsálẹ́mù

   

13:23-35

 

Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Pèríà

Ó kọ́ni ní ìwà ìrẹ̀lẹ̀; àwọn àpèjúwe: ibi tó lọ́lá jù àtàwọn tí wọ́n pè tó ń ṣàwáwí

   

14:1-24

 

Ronú lórí ohun tó máa náni láti di ọmọ ẹ̀yìn

   

14:25-35

 

Àwọn àpèjúwe: àgùntàn tó sọ nù, ẹyọ owó tó sọ nù, ọmọkùnrin tó sọ nù

   

15:1-32

 

Àwọn àpèjúwe: ìríjú aláìṣòdodo, ọkùnrin ọlọ́rọ̀ àti Lásárù

   

16:1-31

 

Ẹ̀kọ́ nípa ìkọsẹ̀, ìdáríjì àti ìgbàgbọ́

   

17:1-10

 

Bẹ́tánì

Lásárù kú, ó sì jíǹde

     

11:1-46

Jerúsálẹ́mù; Éfúrémù

Wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù; ó kúrò níbẹ̀

     

11:47-54

Samáríà; Gálílì

Ó wo adẹ́tẹ̀ mẹ́wàá sàn; ó sọ bí Ìjọba Ọlọ́run ṣe máa dé

   

17:11-37

 

Samáríà tàbí Gálílì

Àwọn àpèjúwe: opó tí kò yéé bẹ̀bẹ̀, Farisí àti agbowó orí

   

18:1-14

 

Pèríà

Ó kọ́ni nípa ìgbéyàwó àti ìkọ̀sílẹ̀

19:1-12

10:1-12

   

Ó súre fún àwọn ọmọdé

19:13-15

10:13-16

18:15-17

 

Ìbéèrè ọkùnrin ọlọ́rọ̀ náà; àpèjúwe nípa àwọn òṣìṣẹ́ ọgbà àjàrà àti owó iṣẹ́ wọn tó dọ́gba

19:16–20:16

10:17-31

18:18-30

 

Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Pèríà

Ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ nígbà kẹta

20:17-19

10:32-34

18:31-34

 

Jémíìsì àti Jòhánù fẹ́ gba ipò nínú Ìjọba Ọlọ́run

20:20-28

10:35-45

   

Jẹ́ríkò

Jẹ́ríkò Ó gba ibẹ̀ kọjá, ó la ojú ọkùnrin méjì tó jẹ́ afọ́jú; ó lọ sọ́dọ̀ Sákéù; àpèjúwe mínà mẹ́wàá

20:29-34

10:46-52

18:35–19:28