Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

B9

Àwọn Agbára Ayé Tí Dáníẹ́lì Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Wọn

Bábílónì

Dáníẹ́lì 2:32, 36-38; 7:4

607 Ṣ.S.K. Ọba Nebukadinésárì pa Jerúsálẹ́mù run

Mídíà àti Páṣíà

Dáníẹ́lì 2:32, 39; 7:5

539 Ṣ.S.K. Wọ́n ṣẹ́gun Bábílónì

537 Ṣ.S.K. Kírúsì pàṣẹ pé káwọn Júù pa dà sí Jerúsálẹ́mù

Gíríìsì

Dáníẹ́lì 2:32, 39; 7:6

331 Ṣ.S.K. Alẹkisáńdà Ńlá ṣẹ́gun Páṣíà

Róòmù

Dáníẹ́lì 2:33, 40; 7:7

63 Ṣ.S.K. Ó ṣàkóso ilẹ̀ Ísírẹ́lì

70 S.K. Ó pa Jerúsálẹ́mù run

Gẹ̀ẹ́sì àti Amẹ́ríkà

Dáníẹ́lì 2:33, 41-43

1914 sí 1918 S.K. Nígbà Ogun Àgbáyé Kìíní, Agbára Ayé Gẹ̀ẹ́sì àti Amẹ́ríkà bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàkóso