Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn àlùfáà gbé àpótí májẹ̀mú bí wọ́n ṣe ń lọ sínú Odò Jọ́dánì

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Nígbàgbọ́

Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Nígbàgbọ́

Ó lè dà bíi pé àwọn ìtọ́ni Jèhófà ò bọ́gbọ́n mu nígbà míì (Joṣ 3:12, 13; it-2 105; wo àwòrán iwájú ìwé)

Ó yẹ káwọn alábòójútó máa múpò iwájú tó bá dọ̀rọ̀ ká tẹ̀ lé ìtọ́ni (Joṣ 3:14; w13 9/15 16 ¶17)

Jèhófà máa ń bù kún àwọn tó bá pinnu láti ṣe ohun tó tọ́ (Joṣ 3:15-17; w13 9/15 16 ¶18)

Jèhófà máa bù kún wa tá a bá ṣe gbogbo ohun tá a lè ṣe láti wàásù, kódà tí ìlera wa tàbí ipò tá a wà ò bá jẹ́ ká lè ṣe tó bá a ṣe fẹ́.