ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Jẹ́ Kí Jèhófà Fi “Ọwọ́ Ayérayé” Rẹ̀ Dáàbò Bò Ẹ́

Yorùbá
Jẹ́ Kí Jèhófà Fi “Ọwọ́ Ayérayé” Rẹ̀ Dáàbò Bò Ẹ́
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021322/univ/art/202021322_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 September ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jẹ́ Kí Jèhófà Fi “Ọwọ́ Ayérayé” Rẹ̀ Dáàbò Bò Ẹ́

Jẹ́ Kí Jèhófà Fi “Ọwọ́ Ayérayé” Rẹ̀ Dáàbò Bò Ẹ́

Jèhófà fẹ́ ká jẹ́ adúróṣinṣin (Di 33:26; it-2 51)

Ó máa ń wù ú láti lo agbára rẹ̀ nítorí wa (Di 33:27; rr 120, àpótí)

Bíi ti Mósè, ó yẹ ká gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà pé ó máa gbà wá là (Di 33:29; w11 9/15 19 ¶16)

Jèhófà máa ń fi ọwọ́ ayérayé rẹ̀ dáàbò bò wá tá a bá wà nínú ìṣòro. Bóyá nígbà tá à ń ṣàìsàn, tá a sorí kọ́, tá à ń ṣọ̀fọ̀ tàbí nígbà tá a ṣàṣìṣe àmọ́ tá a ronú pìwà dà.