ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní September-October 2021

Yorùbá
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ Lóde Ẹ̀rí ní September-October 2021
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021343/univ/art/202021343_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 September ojú ìwé 16

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Nígbà Àkọ́kọ́

Ìbéèrè: Ibo la ti lè rí ìmọ̀ràn tó dáa nípa bá a ṣe lè máa gbé ìgbé ayé wa?

Bíbélì: 2Ti 3:16, 17

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tó fi yẹ kó o gbára lé Bíbélì?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

Ìpadàbẹ̀wò

Ìbéèrè: Kí nìdí tó fi yẹ kó o gbára lé Bíbélì?

Bíbélì: Job 26:7

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn ìbéèrè wo ni Bíbélì dáhùn?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: