ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Jèhófà Jà Fáwọn Ọmọ Ísírẹ́lì

Yorùbá
Jèhófà Jà Fáwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021335/univ/art/202021335_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 September ojú ìwé 10

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Jà Fáwọn Ọmọ Ísírẹ́lì

Jèhófà Jà Fáwọn Ọmọ Ísírẹ́lì

Àwọn ọba márùn-ún kóra jọ láti bá Gíbíónì àti Ísírẹ́lì jà (Joṣ 10:5; it-1 50)

Jèhófà pa àwọn ọba márààrún (Joṣ 10:10, 11; it-1 1020)

Jèhófà mú kí oòrùn dúró sójú kan (Joṣ 10:12-14; w04 12/1 11 ¶1)

Tá a bá ń kojú àtakò, ó dá wa lójú pé Jèhófà máa ràn wá lọ́wọ́ ká lè jẹ́ adúróṣinṣin. A mọ̀ pé lọ́lá ìtìlẹyìn Jèhófà, kò sí ìjọba èyíkéyìí tó lè fòpin sí ìjọsìn wa.