ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI

Yẹra Fáwọn Nǹkan Tí Kò Ní Láárí

Yorùbá
Yẹra Fáwọn Nǹkan Tí Kò Ní Láárí
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202021331/univ/art/202021331_univ_sqr_xl.jpg
mwb21 September ojú ìwé 8

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Yẹra Fáwọn Nǹkan Tí Kò Ní Láárí

Yẹra Fáwọn Nǹkan Tí Kò Ní Láárí

Ojúkòkòrò mú kí Ákánì mú nǹkan tí kì í ṣe tiẹ̀ (Joṣ 7:1, 20, 21; w10 4/15 20 ¶5)

Ohun tí Ákánì ṣe ṣàkóbá fún ìdílé ẹ̀ àti orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì lápapọ̀ (Joṣ 7:4, 5, 24-26; w97 8/15 28 ¶2)

A gbọ́dọ̀ máa kó ara wa níjàánu (1Jo 2:15-17; w10 4/15 21 ¶8)

A gbọ́dọ̀ yẹra fáwọn nǹkan tí kò ní láárí, torí pé wọn ò ní wúlò nínú ayé tuntun.—2Pe 3:13.