Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 TÍMÓTÌ 1-3

Iṣẹ́ Rere Ni Kó O Máa Lé

Iṣẹ́ Rere Ni Kó O Máa Lé

3:1, 13

Àtikékeré ló ti dáa jù káwọn arákùnrin ti máa ran ìjọ lọ́wọ́. Èyí máa ràn wọ́n lọ́wọ́ láti gba ìdálẹ́kọ̀ọ́, bí wọ́n sì ṣe ń dàgbà sí i, ó máa túbọ̀ ṣe kedere pé wọ́n ti ń tóótun láti di ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́. (1Ti 3:10) Báwo ni arákùnrin kan ṣe lè máa lé iṣẹ́ rere? Wọ́n lè ṣe bẹ́ẹ̀ tí wọ́n bá ń fi àwọn ànímọ́ yìí sílò:

  • Máa yọ̀ǹda ara rẹ.​—km 7/13 2-3 ¶2

  • Jẹ́ ẹni tẹ̀mí.​—km 7/13 3 ¶3

  • Jẹ́ olóòótọ́ àti ẹni tó ṣeé fọkàn tán.​—km 7/13 3 ¶4