Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ July 8-​14, 2019
/assets/ct/08c9985de2/images/syn_placeholder_sqr.png

July 8-​14

1 TẸSALÓNÍKÀ 1-5

July 8-​14
  • Orin 90 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 1)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 4)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 81

  • Àwọn Aṣáájú-Ọ̀nà Máa Ń Fún Àwọn Míì Níṣìírí: (9 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Àwọn Aṣáájú-Ọ̀nà Ń Ṣe Bẹbẹ. Lẹ́yìn náà kẹ́ ẹ dáhùn àwọn ìbéèrè yìí: Báwo ni àwọn aṣáájú-ọ̀nà ṣe lè fún àwọn ará ìjọ níṣìírí? Ìṣírí wo lo ti rí gbà látọ̀dọ̀ àwọn aṣáájú-ọ̀nà tó wà nínú ìjọ rẹ?

  • Àwọn Àpẹẹrẹ Rere Tó Lè Fún Wa Níṣìírí: (6 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà A Gbọ́dọ̀ ‘Fi Ìfaradà Sáré’​—Máa Tẹ̀ Lé Àwọn Àpẹẹrẹ Rere. Lẹ́yìn náà kẹ́ ẹ dáhùn àwọn ìbéèrè yìí: Ìṣòro wo ni arábìnrin yẹn ní? Kí ló ṣe tó fi rí ìṣírí gbà?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 8 ¶1-7

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 100 àti Àdúrà