ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 TÍMÓTÌ 4-6 Ìfọkànsin Ọlọ́run Tàbí Ọrọ̀ TẸ̀ Ẹ̣́ Ìfọkànsin Ọlọ́run Tàbí Ọrọ̀ 6:6-10 Báwo ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe fi hàn pé a máa túbọ̀ láyọ̀ tá a bá gbájú mọ́ ìjọsìn Jèhófà dípò ọrọ̀? Ọ̀pọ̀ ìbùkún ló ń dúró de àwọn tó bá tẹ́wọ́ gba iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún Onw 5:10 Onw 5:12 Mt 5:3 Iṣe 20:35 Kí nìdí tí kò fi ṣeé ṣe láti máa jọ́sìn Jèhófà ká tún máa wá ọrọ̀? (Mt 6:24) Pa Dà Èyí Tó Kàn