Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ July 22-​28, 2019
/assets/ct/08c9985de2/images/syn_placeholder_sqr.png

July 22-​28

1 TÍMÓTÌ 1-3

July 22-​28
  • Orin 103 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Iṣẹ́ Rere Ni Kó O Máa Lé”: (10 min.)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • 1Ti 1:4​—Kí nìdí tí Pọ́ọ̀lù fi kìlọ̀ fún Tímótì pé kó má tẹ́tí sí àwọn ìtàn ìdílé? (it-1 914-915)

    • 1Ti 1:17​—Kí nìdí tó fi jẹ́ pé Jèhófà nìkan la lè pè ní “Ọba ayérayé”? (cl 12 ¶15)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Ti 2:1-15 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 137

  • Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ṣiṣẹ́ ní Warwick Bọlá fún Jèhófà: (6 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà (lára àwọn fídíò tó wà ní abala IṢẸ́ WA). Lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí:

    Báwo ni àwọn ọ̀dọ́ Ẹlẹ́rìí ṣe ṣèrànwọ́ nígbà tá à ń kọ́ Bẹ́tẹ́lì tó wà ní Warwick, àǹfààní wo ni wọ́n sì rí níbẹ̀?

    Àwọn àǹfààní wo làwọn ọ̀dọ́kùnrin àtàwọn ọ̀dọ́bìnrin tó wà nínú ìjọ ní láti fi bọlá fún Jèhófà?

  • “Ẹ̀kọ́ Wo Lo Rí Kọ́ Lára Wọn?”: (9 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Bọ̀wọ̀ Fún Àwọn Ọkùnrin Onírìírí.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 8 ¶16-22

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 115 àti Àdúrà