Yorùbá
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni ti Ọ̀sẹ̀ July 29–​August 4, 2019
/assets/ct/fa815d8e9f/images/syn_placeholder_sqr.png

July 29–​August 4

1 TÍMÓTÌ 4-6

July 29–​August 4
  • Orin 80 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ìfọkànsin Ọlọ́run Tàbí Ọrọ̀”: (10 min.)

    • 1Ti 6:6-8​—Èrè tó wà nínú “ìfọkànsin Ọlọ́run [pẹ̀lú] ìtẹ́lọ́rùn” (w03 6/1 9 ¶1-2)

    • 1Ti 6:9​—Ohun tó máa ń yọrí sí téèyàn bá pinnu láti di ọlọ́rọ̀ (g 7/07 28 ¶1)

    • 1Ti 6:10​—Ìrora tí ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ owó máa ń ní (g 1/09 6 ¶4-6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • 1Ti 4:2​—Báwo lẹnì kan ṣe lè dá àpá sí ẹ̀rí ọkàn rẹ̀, kí sì nìdí tí èyí fi léwu? (lv 21-22 ¶17)

    • 1Ti 4:13 àlàyé ìsàlẹ̀​—Kí nìdí tí Pọ́ọ̀lù fi gba Tímótì níyànjú láti máa tẹra mọ́ kíkàwé ní gbangba? (it-2 714 ¶1-2)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Ti 4:1-16 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI