JÍ! July 2015 | Ohun Márùn-Ún Tó Máa Mú Kí Ìlera Rẹ Dára Sí I

O lè ṣe ohun tó máa dín àìsàn kù tàbí ohun tí kò ní jẹ kó o ṣe àìsàn rárá.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ohun Tó Máa Mú Kí Ìlera Rẹ Dára Sí I

Ohun márùn-ún tó o lè ṣe báyìí kí ìlera rẹ lè dára sí i

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Láti Máa Gbọ́ràn

Tó bá ṣẹlẹ̀ pé gbogbo ìgbà ni ọmọ rẹ máa ń kọ ọ̀rọ̀ sí ẹ lẹ́nu, kí lo lè ṣe? Ohun márùn-ún wà tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́.

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Ìwà Ipa

Irú ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo àwọn oníwà ipá? Ṣé àwọn oníwà ipa lè yíwà pa dà?

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bí Ìfẹ́ Yín Ṣe Lè Jinlẹ̀ Sí I

Ṣé ìfẹ́ tó o ní fún ọkọ tàbí aya rẹ mú kí ìdílé yín dúró sán-ún?

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Pansaga

Ṣé panṣágà lè tú ìgbéyàwó ká?

OHUN TÓ Ń LỌ LÁYÉ

Nípa Àyíká

Àwọn ìròyìn lọ́ọ́lọ́ọ́ ń gbé ìbéèrè náà dìde pé, “Kí ló dé táwọn èèyàn ò fi rí nǹkan kan ṣe sọ́rọ̀ àyíká tó ń bà jẹ́?”

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Olè Ò Dáa

Ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo olè jíjà? Ka Ẹkísódù 20:15. Wo fídíò yìí kí ìwọ àti Kọ́lá jọ kẹ́kọ̀ọ́ sí i.