Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

MARCH 4, 2022
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #2

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #2

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ bí àwọn ará wa lọ́kùnrin àti lóbìnrin ṣe dúró lórí ìgbàgbọ́ wọn bó tiẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ní ọ̀pọ̀ ìṣòro.