Ìròyìn
Gbé e jáde 46 - 60 of 738
Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #10
Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ bí nǹkan ṣe ń lọ lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn àti bá a ṣe lè lo àkókò wa lọ́nà tó dáa.
Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #9
Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fún àwọn ará níṣìírí, ó sì tún jẹ́ ká gbọ́rọ̀ lẹ́nu àwọn ará tó ti bẹ̀rẹ̀ sí í ṣèpàdé ní Gbọ̀ngàn Ìjọba.
Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #8
Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ lẹ́nu àìpẹ́ yìí, ó sì tún sọ ẹsẹ Ìwé Mímọ́ ti ọdún 2022.
Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #7
Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí gbà wá níyànjú pé ká máa wà níṣọ̀kan.
Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #6
Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fún àwọn àgbàlagbà níṣìírí, ó sì sọ fún wa bí nǹkan ṣe ń lọ sí lẹ́nu iṣẹ́ ìkọ́lé.
Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #5
Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí fún àwọn ìdílé ní ìṣírí, ó sì sọ ìrírí tó máa jẹ́ káwọn ìdílé lè fara da àsìkò àjàkálẹ̀ àrùn yìí.
Gbé e jáde 46 - 60 of 738

