Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

DECEMBER 17, 2021
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #10

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #10

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ bí nǹkan ṣe ń lọ lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn Corona. Ó tún sọ àwọn ìrírí tó wúni lórí, tó sì jẹ́ ká rí bá a ṣe lè lo àkókò wa lọ́nà tó dáa lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn yìí.