NOVEMBER 12, 2021
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #9

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2021 #9

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ̀rọ̀ lórí bí Jèhófà ṣe ń darí ètò ẹ̀ lásìkò àjàkálẹ̀ àrùn yìí. Ó tún jẹ́ ká mọ bínú àwọn ará ṣe dùn tó sí ètò tá a ṣe pé káwọn ìjọ kan bẹ̀rẹ̀ sí í ṣèpàdé ní Gbọ̀ngàn Ìjọba.