ILÉ ÌṢỌ́ December 2015 | O Lè Lóye Bíbélì

Ǹjẹ́ o ti ṣe kàyéfì rí pé, ‘Kí ló dé tí Bíbélì fi ṣòro lóye?’

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Lóye Bíbélì?

Ọ̀p gbà pé ọba ìwé ni Bíbélì láìmọ bí wọ́n ṣe lè jàǹfààní nínú rẹ̀.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ìwé Kan Tó Yẹ Ká Mọ̀ Dunjú

Ohun mẹ́rin tó jẹ́ ká mọ̀ pé ó yẹ kí gbogbo wa mọ Bíbélì dunjú.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ohun Tó Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Lóye Bíbélì

Tó bá jẹ́ pé wọ́n kọ Bíbélì lọ́nà tá a máa gbà lóye rẹ̀, ṣé ó tún yẹn kẹ́nì kan ràn wá lọ́wọ́ ká tó lóye rẹ̀?

Ṣé Ìwà Àgàbàgebè Lè Dópin?

Ṣé ìwà àgàbàgebè táwọn olóṣèlú, aṣáájú ìsìn àtàwọn oníṣòwò ń hù ń kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ?

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Ṣé “láti gbogbo orílẹ̀-èdè àwọn tí ń bẹ lábẹ́ ọ̀run” ni àwọn Júù ti wá sí Jerúsálẹ́mù ní Pẹ́ńtíkọ́sì ọdún 33 Sànmánì Kristẹni? Ibo làwọn tó wá dé sí?

Ṣé Pétérù Ni Póòpù Àkọ́kọ́?

Kí ni Jésù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé: “Peteru ni ọ́, ní orí àpáta yìí ni n óo kọ́ ìjọ mi lé”?

ÀWỌN ÒǸKÀWÉ WA BÉÈRÈ PÉ

Kí Ló Burú Nínú Ọdún Kérésì?

Tí àwọn àṣà Kérésì bá tiẹ̀ wá látọ̀dọ̀ àwọn abọ̀rìṣà, ṣé ìyẹn wá ní kéèyàn máà lọ́wọ́ sí i?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kí nìdí tí Ọlọ́run fi máa ń tẹ́wọ́ gba àwọn tó nífẹ̀ẹ́ sí òtítọ́?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Bá Ohun Tí Bíbélì Sọ Mu?

Ṣé àwọn ohun tí kì í ṣe òótọ́ nínú ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì wà nínú Bíbélì?