Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ṣé Ó Wù Ẹ́ Kó O Mọ Bíbélì Dáadáa?

Ṣé Ó Wù Ẹ́ Kó O Mọ Bíbélì Dáadáa?

Kò pọn dandan kó o ní

  • Ọgbọ́n àrà ọ̀tọ̀

  • Owó

  • Tàbí kó o kàn gba ohun tí wọ́n bá ti sọ gbọ́

Ohun tó o nílò

  • “Agbára ìmọnúúrò.”​—Róòmù 12:1

  • Ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀

Àwọn ohun tó o máa kọ́ nínú Bíbélì máa yà ẹ́ lẹ́nu.