JÍ! March 2013 | Ọ̀rọ̀ Pàtàkì fún Àwọn Tó Fẹ́ Ṣí Lọ sí Ìlú Míì

Àwọn ìṣòro wo làwọn tó ṣí lọ sí ìlú míì máa ń ní tí wọ́n bá débẹ̀?

Ohun Tó Ń Lọ Láyé

Mọ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó gbàfiyèsí tó wáyé láìpẹ́ yìí yíká ayé.

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bí Ẹ Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Bíbá Ara Yín Jiyàn

Ṣé ìwọ àti ẹnì kejì rẹ máa ń jiyàn ní gbogbo ìgbà? Wo bí àwọn ìlànà Bíbélì ṣe lè ran ìdílé yín lọ́wọ́.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ọ̀rọ̀ Pàtàkì Fún Àwọn Tó Fẹ́ Ṣí Lọ sí Ìlú Míì

Tó o bá kó lọ sí orílẹ̀-èdè míì, ṣe ìyẹn fi han pé ìdílé rẹ máa láyọ̀?

ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ

Ẹnì Kan Tó Ń Ṣe Rọ́bọ́ọ̀tì Sọ Ìdí Tó Fi Gba Ọlọ́run Gbọ́

Professor Massimo Tistarelli sọ ìdí tó fi yí èrò nípa ẹfolúṣọ̀n pa dà.

ÌTÀN ÀTIJỌ́

Plato

Ka ohun tó mú kí wọ́n da èrò Plato pọ̀ mọ́ ẹ̀kọ́ Kristẹni.

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Àwọn Aláìní

Ka ohun tí Ọlọ́run ṣe láti fi han pé ọ̀rọ̀ àwọn aláìní jẹ òun lógún.

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Ìrù Aláǹgbá Adárípọ́n

Báwo ni aláǹgbá yìí ṣe máa ń fò láti ibi tó tẹ́jú pẹrẹsẹ sí ara ògiri?