Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìròyìn Kárí Ayé

 

2016-06-27

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìdúróṣinṣin ni Àpéjọ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ọdún 2016 Dá Lé

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe Àpéjọ Àgbègbè tí àkòrí rẹ̀ sọ pé “Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà!” kárí ayé. Gbogbo èèyàn la pè sí àpèjọ ọlọ́jọ́-mẹ́ta yìí, ọ̀fẹ́ sì ni.

2016-05-18

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ń Pe Gbogbo Èèyàn Kárí Ayé sí Ìrántí Ikú Kristi Tá A Máa Ń Ṣe Lọ́dọọdún

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa bẹ̀rẹ̀ sí í pé gbogbo èèyàn kárí ayé síbi Ìrántí Ikú Kristi tí wọ́n máa ń ṣe lọ́dọọdún, ó máa wáyé ní March 23, 2016.

2016-05-04

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Sọ Nípa Àpéjọ Wọn Tọdún 2015 Tó Máa Bẹ̀rẹ̀ Síí Wáyé Láti Oṣù May

Àpéjọ àgbègbè “Máa Tẹ̀lé Àpẹẹrẹ Kristi!” tọdún 2015 táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe máa kọ́ wa bá a ṣe lé jàǹfààní nípa títẹ̀lé àpẹẹrẹ Jésù. Àpéjọ àgbègbè yìí máa bẹ̀rẹ̀ láti oṣù May ọdún 2015 títí di oṣù January ọdún 2016 ní ìlú ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ kárí ayé.

2016-05-04

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

À Ń Retí Ogún Mílíọ̀nù Èèyàn Níbi Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe ìkéde kárí ayé láti pe àwọn èèyàn tó pọ̀ gan an wá síbi Ìrántí ikú Kristi tó máa wáyé lọ́jọ́ kẹta oṣù April, ọdún 2015.