Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àkànṣe Ìpàtẹ Bíbélì

Àkànṣe Ìpàtẹ Bíbélì

Wo fídíò yìí kó o lè mọ ìtàn nípa àkànṣe ìpàtẹ Bíbélì tó wà ní oríléeṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. Ìpàtẹ náà sọ ìtàn nípa orúkọ Ọlọ́run tó wà nínú Bíbélì.