Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìrántí Ikú Jésù

Ìrántí Ikú Jésù

Ọdọọdún ni àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń ṣe ìrántí ikú Jésù bó ṣe sọ pé ká máa ṣe é. (Lúùkù 22:19, 20) Inú wa dùn láti pè ọ́ pé kó o wá ká jọ ṣe ohun pàtàkì tí Jésù dá sílẹ̀ yìí. Wàá kọ́ nípa bí ìgbésí ayé Jésù àti ikú rẹ̀ ṣe lè ṣe ọ́ láǹfààní.