Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ẹ̀kọ́ 1

Ẹ̀kọ́ 1

Ẹ̀kọ́ 1

Ìṣípayá 4:11

Ta ló dá ayé?

Ta ló dá òkun?

Ta ló dá ìwọ àti èmi?

Ta ló dá labalábá pẹ̀lú ìyẹ́ rẹ̀ aláràbarà?

Jèhófà Ọlọ́run ló dá ohun gbogbo.

IṢẸ́ ÒBÍ

Ka ẹsẹ Bíbélì yìí fún ọmọ rẹ:

Ìṣípayá 4:11

Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:

Àwọn ìràwọ̀ Ojú ọ̀run Oòrùn

Ọkọ̀ ojú omi Ayé Ilé

Òkun Labalábá

Bi ọmọ rẹ pé:

Kí ni orúkọ Ọlọ́run?

Ibo ni Jèhófà ń gbé?

Kí ni Jèhófà dá?

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 4, 5]