Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ṣé Ọlọ́run Fẹ́ Ká Máa Lo Ère Nínú Ìjọsìn?

Ṣé Ọlọ́run Fẹ́ Ká Máa Lo Ère Nínú Ìjọsìn?

A ò lè rí Ọlọ́run. Báwo la ṣe wá lè sún mọ́ ọn nígbà tá ò lè rí i? Ṣé ó burú tá a bá ń lo ère nínú ìjọsìn ká lè túbọ̀ sún mọ́ Ọlọ́run?