Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Hungary

 

2016-05-09

HUNGARY

Iléeṣẹ́ Holocaust Memorial Center Lórílẹ̀-èdè Hungary Ṣí Àmì Ẹ̀yẹ Kan Láti Fi Yẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tí Ìjọba Násì Pa Sí

Wọ́n ṣí àmì ẹ̀yẹ kan ní iléeṣẹ́ Holocaust Memorial Center nílùú Budapest láti fi rántí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mẹ́rin tí wọ́n pa torí ẹ̀rí ọkàn ò gbà wọ́n láyè láti ṣiṣẹ́ ológun nígbà Ogun Àgbáyé Kejì.