Àwọn Ìpàdé Pàtàkì

ÀWỌN ÌPÀDÉ PÀTÀKÌ

Àpéjọ Àgbègbè Táwọn Tagalog ṣe ní Róòmù​—“Gbogbo Ìdílé Tún Wà Pa Pọ̀!”

Àpéjọ àgbègbè ọlọ́jọ́ mẹ́ta àkọ́kọ́, tí wọ́n ṣe lédè Tagalog, ni ọ̀pọ̀ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní Yúróòpù wá sí.

Ó Ń Ṣe Wá Bíi Kípàdé Náà Má Parí

Wo ojúlówó ìfẹ́ àti ìṣọ̀kan tó wà láàárín àwọn tó wá látinú oríṣiríṣi ẹ̀yà, èdè, àtorílẹ̀-èdè ní àkànṣe Àpéjọ Àgbègbè tá a ṣe nílùú Yangon, Myanmar.