Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Orin 89—Gbọ́, Ṣègbọràn, Kó O sì Gba Ìbùkún

Orin 89—Gbọ́, Ṣègbọràn, Kó O sì Gba Ìbùkún

A lè di ọ̀rẹ́ Jèhófà tí a bá ń kọrin. Kí ìwọ pẹ̀lú Kọ́lá àti Tósìn jọ kọrin nípa àwọn ìbùkún tá a máa gbà tá a bá ń ṣègbọràn sí Jèhófà.

 

O Tún Lè Wo

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.