Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ATỌ́NÀ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Má Ṣe Kúrò Nínú Ìfẹ́ Ọlọ́run (Apá 1)

Orí 19 ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Kí ló túmọ̀ sí láti nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run? Kí ló ń mú kó wu Kristẹni kan láti nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run?