Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Èèyàn—Máa Sọ Wọ́n Dọmọ Ẹ̀yìn

A ṣe ìwé yìí kó o lè mọ bí wàá ṣe ní àwọn ìwà tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ.