Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì

A ṣe ìwé yìí kó o lè fi bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ Bíbélì. Ó jẹ́ ara ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ Bíbélì tá a gbé kalẹ̀.

O Tún Lè Wo

ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ

Kí Ni Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn?

Ìtumọ̀ Bíbélì èyíkéyìí tó bá wù ẹ́ lo lè lò láti fi kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. O sì lè pe gbogbo ìdílé ẹ tàbí kó o pe àwọn ọ̀rẹ́ ẹ wá síbi ìkẹ́kọ̀ọ́ náà.