Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

JÍ! No. 1 2021 | Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Tó Ń Mú Káyé Ẹni Dùn

Gbogbo wa la fẹ́ káyé wa dùn, kó sì dáa. Jẹ́ ká wo bá a ṣe lè rí ọgbọ́n táá mú káyé wa dùn.

 

Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Tó Ń Mú Káyé Ẹni Dùn

Ọlọ́run Olódùmarè fún wa ní ọgbọ́n tó ń mú káyé wa dùn, tó sì máa mú kí ọjọ́ ọ̀la wa dáa.

Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Táá Mú Kí Ìdílé Rẹ Láyọ̀

Kí ni ọkọ, ìyàwó àtàwọn ọmọ lè ṣe táá mú kí ìdílé wọn láyọ̀?

Àwọn Ìlànà Táá Jẹ́ Ká Wà Lálàáfíà Pẹ̀lú Àwọn Èèyàn

Àwọn ìwà àti ìṣe wo ló lè mú ká wà lálàáfíà pẹ̀lú àwọn èèyàn?

Kí Nìdí Tá A Fi Ń Jìyà, Tá À Ń Darúgbó, Tá A sì Ń Kú?

Wo ohun mẹ́rin tó ń mú ká máa jìyà, ká máa darúgbó, ká sì máa kú.

Ẹ̀kọ́ Tó Ń Fini Lọ́kàn Balẹ̀ Pé Ọ̀la Ń Bọ̀ Wá Dáa

Wo díẹ̀ lára àwọn ohun rere tí Ọlọ́run sọ pé ó máa jẹ́ kí ọjọ́ ọ̀la wa dáa.

Ẹ̀kọ́ Tó Ń Jẹ́ Ká Sún Mọ́ Ọlọ́run

Kí ni Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ nípa Ọlọ́run, tó máa jẹ́ kó wù ẹ́ láti mọ̀ ọ́n, kó o sì fẹ́ láti di ọ̀rẹ́ rẹ̀?

Ẹ̀kọ́ Táá Jẹ́ Kó O Di Ọlọ́gbọ́n

Ọlọ́run fẹ́ kó o di ọlọ́gbọ́n. Ṣó o fẹ́ jàǹfààní látinú ọgbọ́n Ọlọ́run?

Ṣó O Fẹ́ Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I?

Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, àwọn fídíò, eré bèbí, ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò àtàwọn àpilẹ̀kọ wà tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè ṣe ìpinnu tó dáa, tó máa jẹ́ kí ayé ẹ dùn.