Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ṣé Òpin Ayé Ti Dé Tán?

Ṣé Òpin Ayé Ti Dé Tán?

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn èèyàn ti sọ oríṣiríṣi àkókò tí wọ́n gbà pé òpin ayé máa dé, síbẹ̀ òpin ayé ò tíì dé! Ṣé òpin ayé máa dé lóòótọ́?

KÍ NI BÍBÉLÌ SỌ?

  • Báwo ni òpin ayé ṣe máa dé?

  • Ìgbà wo ló máa dé?

  • Ṣé wàá la òpin ayé já?

  • Báwo ni ayé ṣe máa rí lẹ́yìn tí òpin bá dé?

A rọ̀ ẹ́ pé kó o ka ìwé yìí, kó o lè rí ọ̀nà tí Bíbélì gbà dáhùn àwọn ìbéèrè yìí. Àwọn ìdáhùn yẹn máa yà ẹ́ lẹ́nu, ó sì máa fi ẹ́ lọ́kàn balẹ̀.

Inú àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa dùn láti jẹ́ kó o mọ̀ sí i nípa ohun tí Ọlọ́run fẹ́ ṣe fún aráyé.