ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ September 2022

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti November 7–December 4, 2022 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 39

Ṣé Orúkọ Ẹ Wà Nínú “Ìwé Ìyè”?

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 40

‘Wọ́n Ń Sọ Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Di Olódodo’

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Àwọn wo ló máa jí dìde sí ayé, irú àjíǹde wo sì ni wọ́n máa ní?

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Kí ni àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé “ẹni tí a bí ní kògbókògbó” lòun? (1 Kọ́ríńtì 15:8)