ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ October 2025
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti December 8, 2025–January 4, 2026 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
1925—Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn
Kí làwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ń retí kó ṣẹlẹ̀ lọ́dún 1925? Báwo sì ni wọ́n ṣe gbájú mọ́ iṣẹ́ ìwàásù, bó tiẹ̀ jẹ́ pé ohun tí wọ́n ń retí ò ṣẹlẹ̀?
ÀPILẸ̀KỌ 41
Ìfẹ́ Tí Ọlọ́run Ní sí Wa Ń Jẹ́ Ká Lè Fara Da Ìṣòro
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 15-21, 2025.
ÀPILẸ̀KỌ 42
Bó O Ṣe Lè Gbàdúrà sí Jèhófà Látọkàn Wá
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 22-28, 2025.
ÀPILẸ̀KỌ 43
Máa Rántí Gbàdúrà Fáwọn Ará
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 29, 2025–January 4, 2026.
Àwọn Arákùnrin Méjì Tó Ṣẹ̀ṣẹ̀ Di Ara Ìgbìmọ̀ Olùdarí
Ẹ jẹ́ ká mọ àwọn Arákùnrin Méjì Tó Ṣẹ̀ṣẹ̀ Di Ara Ìgbìmọ̀ Olùdarí. Àwọn ni Jody Jedele àti Jacob Rumph. Ó ti pẹ́ gan-an táwọn arákùnrin méjèèjì yìí ti ń sin Jèhófà tọkàntọkàn.
OHUN TÓ O LÈ FI KẸ́KỌ̀Ọ́
Ohun Táá Jẹ́ Kó O Máa Ka Bíbélì Lójoojúmọ́
Wo àwọn nǹkan díẹ̀ tó o lè ṣe táá jẹ́ kó o máa ka Bíbélì lójoojúmọ́.

