ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ May 2024

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti July 8–​August 11, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 18

Fọkàn Tán Ọlọ́run Aláàánú Tó Jẹ́ “Onídàájọ́ Gbogbo Ayé”!

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní July 8-14, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 19

Kí La Mọ̀ Nípa Bí Jèhófà Ṣe Máa Ṣèdájọ́ Lọ́jọ́ Iwájú?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní July 15-21, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 20

Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Mú Kó O Máa Wàásù Nìṣó

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní July 22-28, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 21

Báwo Lo Ṣe Lè Rí Ẹni Tó O Máa Fẹ́?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní July 29–​August 4, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 22

Bó O Ṣe Lè Mọ̀ Bóyá Kó O Fẹ́ Ẹnì Kan Tàbí Kó O Má Fẹ́ Ẹ

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní August 5-11, 2024.