ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ January 2022

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti February 28–April 3, 2022 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 2

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àbúrò Jésù

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3

Kí La Rí Kọ́ Nínú Bí Jésù Ṣe Sunkún?

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 4

Ìdí Tá A Fi Ń Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi