ÌWÉ ÌRÒYÌN April 8, 2003 Àkóbá Tí Oògùn Olóró Ń Ṣe fún Àwọn Ọ̀dọ́ Bí O Ṣe Lè Dáàbò Bo Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Lílo Oògùn Olóró Ayé Kan Tó Bọ́ Lọ́wọ́ Oògùn Olóró Yóò Dé Láìpẹ́ Oorun—Ṣé Fáwọn Olóòrayè ni Àbí Ohun Àìgbọ́dọ̀máṣe? Bí O Ṣe Lè Túbọ̀ Máa Sùn Dáadáa Báwo ni Mo Ṣe Lè Yan Àwọn Fídíò Orin Tó Bójú Mu? Ohun Tó Ṣẹlẹ̀ Nígbà Tí Iléeṣẹ́ Kan Tó Ń Ṣe Kẹ́míkà Bú Gbàù Mo Ṣèbẹ̀wò Sí Oko Ọ̀gẹ̀dẹ̀ Ọ̀kan Lára Àwọn Èso Tó Wúlò Jù Lọ Lórí Ilẹ̀ Ayé Kí ni Ìfẹ́ Ọrọ̀ Àlùmọ́ọ́nì?