Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kẹtàlélọ́gọ́rin Ti jí!

Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kẹtàlélọ́gọ́rin Ti jí!

Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kẹtàlélọ́gọ́rin Ti jí!

ÀJỌṢE Ẹ̀DÁ

Àwọn Abiyamọ, 4/8

Àwọn Ìdílé Olóbìí Kan, 10/8

Ìgbéyàwó—Ìdè Tó Yẹ Kó Wà Pẹ́ Títí, 2/8

Ìtùnú fún Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀, 5/8

Ọjọ́ Ìgbéyàwó, 2/8

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

A Bù Kún Ìdánúṣe Rẹ̀ (ọ̀dọ́langba kan tó jẹ́ ọmọléèwé), 5/8

Ilẹ̀ Gíríìsì Ti Fàyè Gba Òmìnira Ẹ̀sìn, 12/8

Iṣẹ́ Àfiṣèrànwọ́ Kan Tó Fa Kíki (Texas, Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà), 12/8

Lílo Jí! Lọ́nà Tó Dára, 9/8

Ọ̀dọ́ Kan Tó Fi Ìsìn Rẹ̀ Yangàn, 1/8

Ṣé Inú Rẹ Á Dùn Láti Rí Ìtùnú Gbà? 1/8

ÀWỌN ẸRANKO ÀTI OHUN Ọ̀GBÌN

Bí Ojú Ẹyẹ Idì Ṣe Lágbára Tó, 1/8

Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Abilà, 3/8

Kòkòrò Tó Ń Palẹ̀ Pàǹtírí Mọ́, 9/8

Ohun Ọ̀sìn Àtàtà Ni àbí Panipani Ẹhànnà? 9/8

ÀWỌN OHUN TÓ Ń ṢẸLẸ̀ NÍNÚ AYÉ

Àṣìṣe Tí Kò Tó Nǹkan Máa Ń Di Àjálù Ńlá, 11/8

Àwọn Ìdílé Olóbìí Kan, 10/8

Àwọn Ohun Ìjà Oníkòkòrò Àrùn, 10/8

Àwọn Olùwá-Ibi-Ìsádi, 2/8

Àwọn Tó Yè Bọ́ Nínú Ìsẹ̀lẹ̀, 4/8

Eré Ìdárayá Àwọn Èwe—Ìwà Ipá, 12/8

Ètò Sayé Dọ̀kan, 6/8

Ìbínú Ń Ru Bo Àwọn Èèyàn Lójú, 2/8

Ìfiniṣẹrú, 7/8

Kí Nìdí Tá A Fi Nílò Àwọn Ọlọ́pàá? 7/8

Kíkẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àwọn Ohun Tó Ti Ṣẹlẹ̀ Kọjá, 8/8

Ǹjẹ́ Ó Léwu Láti Wọ Ọkọ̀ Òfuurufú? 12/8

Ọjọ́ Lọjọ́ Tí Ilé Gogoro Méjì Wó ní Amẹ́ríkà, 1/8

Pàǹtírí, 9/8

Ṣé Àlá Tí Kò Lè Ṣẹ Ni Àlàáfíà Kárí Ayé? 5/8

Tẹ́tẹ́ Títa, 8/8

ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ

Alábàágbé, 5/8, 6/8, 7/8

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Wàásù fún Àwọn Ọmọ Iléèwé Mi? 3/8, 4/8

Ewu Wo Ló Wà Nínú Bíbá Ẹ̀mí Lò? 2/8

Ewu Wo Ló Wà Nínú Kí Àwọn Èwe Máa Dájọ́ Àjọròde? 1/8

Ẹ̀mí Ṣohun-Tẹ́gbẹ́-Ń-Ṣe, 12/8

Ẹwà, 8/8

Kí Ló Dé Tí Ọ̀kan Nínú Àwọn Òbí Mi Kò Fi Nífẹ̀ẹ́ Mi Mọ́? 10/8

Ǹjẹ́ Mo Nílò Tẹlifóònù Alágbèérìn? 11/8

ÈTÒ Ọ̀RỌ̀ AJÉ ÀTI IṢẸ́

Àwọn Olùkọ́, 3/8

Ipò Tó Yẹ Ká Fi Iṣẹ́ Sí, 3/8

Mímú Kí Ibi Iṣẹ́ Rẹ Jẹ́ Aláìléwu, 3/8

ÌLERA ÀTI ÌṢÈGÙN

Àrùn Éèdì, 11/8

Àwọn Ọ̀dọ́langba Tó Máa Ń Sùn Ṣáá, 9/8

Ẹ̀jẹ̀ Ríru, 5/8

Ìmọ́lẹ̀ Ọ̀sán, Oorun Dídùn Lóru, 4/8

Irun, 9/8

Kẹ̀kẹ́ Gígùn Ń Ṣeni Láǹfààní, 3/8

Mímú Ara Aláìsàn Lọ́ Wọ́ọ́wọ́ Ṣáájú Iṣẹ́ Abẹ, 7/8

Mo Pàdánù Ọmọ Tí Mi Ò Tíì Bí, 4/8

Oúnjẹ Aṣaralóore, 5/8

Oyin—Ohun Aládùn Tó Ń Wo Ọgbẹ́ Sàn, 3/8

Ṣé Oúnjẹ Rẹ Kò Lè Ṣe Ọ́ Ní Jàǹbá? 1/8

“Títọ́jú Ìkókó Bíi Ti Ẹranko ‘Kangaroo’” (àwọn ìkókó tí oṣù wọn kò pé), 6/8

ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈNÌYÀN

Èbúté Péálì (Ọsirélíà), 4/8

Ibi Ìsádi fún Títẹ Bíbélì (Belgium), 9/8

ÌSÌN

“Àdábọwọ́ Ìsìn,” 5/8

Àdúrà Nítorí Àlàáfíà, 11/8

Ibi Ìsádi fún Títẹ Bíbélì (Belgium), 9/8

Ìjọba Tó Fàyè Gba Onírúurú Ẹ̀sìn (Transylvania), 7/8

Ṣé Lóòótọ́ ni Èṣù Ẹni Ibi Náà Wà? 3/8

Ṣọ́ọ̀ṣì Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì Yapa, 1/8

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Ìgbọ́kànlé Tí Mo Ní Nínú Ọlọ́run Ló Mẹ́sẹ̀ Mi Dúró (R. Sacksioni-Levee), 8/8

Ògbóǹkangí Olóṣèlú Tẹ́lẹ̀ Di Kristẹni Tí Kò Dá Sí Ìṣèlú Mọ́ (L. Šmejkal), 11/8

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Ààbò Ọlọ́run, 4/8

Àwọn Ohun Arùfẹ́-Ìṣekúṣe-Sókè, 7/8

Ayẹyẹ Ọdún Tuntun, 1/8

Ẹ̀kọ́ Ìwalẹ̀pìtàn, 10/8

Irú Àdúrà Tí Ọlọ́run Máa Ń Gbọ́, 9/8

Kérésìmesì, 12/8

Kí Ẹ̀rí Ọkàn Máa Dá Èèyàn Lẹ́bi, 3/8

Máíkẹ́lì Olú-Áńgẹ́lì Náà, 2/8

Ǹjẹ́ Ó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Wàásù? 6/8

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Fọwọ́ Sí Ogun Jíjà? 5/8

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Máa Ń Gbójú Fo Àwọn Kùdìẹ̀-Kudiẹ Èèyàn? 11/8

Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Ìwà Ipá, 8/8

Ọ̀KANKÒJỌ̀KAN

Aṣebi-Ṣoore Ni Iná Jẹ́, 10/8

Fetí Sílẹ̀ Kó O sì Kẹ́kọ̀ọ́, 9/8

Iyọ̀, 6/8

Jàǹbá Ọkọ̀, 9/8

Ǹjẹ́ O Mọ̀? 2/8, 4/8, 6/8, 8/8, 10/8, 12/8

Ṣé Ogun Ló Ń Gbé Lárugẹ Ni? (Alfred B. Nobel), 5/8