Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìgbàgbọ́ Mú Kí Nóà Ṣègbọràn

Wo fídíò yìí kó o lè rí bí Nóà ṣe la ayé burúkú já torí pé ó nígbàgbọ́, ó sì ṣègbọràn sí Jèhófà. Fídíò yìí dá lórí Jẹ́nẹ́sísì 6:1–8:22; 9:8-16.

O Tún Lè Wo

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

Nóà “Bá Ọlọ́run Tòótọ́ Rìn”

Àwọn nǹkan wo ni kò ní jẹ́ kó rọrùn fún Nóà àti aya rẹ̀ láti tọ́ àwọn ọmọ wọn? Báwo ló ṣe jẹ́ pé ìgbàgbọ́ ló mú kí Nóà kan áàkì yẹn?

ILÉ ÌṢỌ́

Ọlọ́run Pa Nóà “Mọ́ Láìséwu Pẹ̀lú Àwọn Méje Mìíràn”

Báwo ni Ọlọ́run ṣe dáàbò bo Nóà àti ìdílé rẹ̀ ní àkókò tó tí ì le jù nínú ìtàn ẹ̀dá?

OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ

Ṣé Ìtàn Àròsọ Lásán Ni Ìtàn Nóà àti Ìkún Omi?

Bíbélì sọ pé ìgbà kan wà tí Ọlọ́run mú kí ìkún omi ńlá kan ṣẹlẹ̀, kó lè fi pa àwọn èèyàn burúkú rún. Àwọn ẹ̀rí wo ló wà nínú Bíbélì tó jẹ́ ká gbà pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni Ìkún Omi náà ti wá lóòótọ́?

ILÉ ÌṢỌ́

Énọ́kù: “Ó Ti Wu Ọlọ́run Dáadáa”

Tó o bá ní bùkátà ìdílé tàbí tó o dojú kọ ìṣòro kan tó gba pé kó o ṣe ohun tó o mọ̀ pé ó tọ́, wàá rí ẹ̀kọ́ kọ́ látinú àpẹẹrẹ ìgbàgbọ́ Énọ́kù.

OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ

Àwọn Wo Làwọn Néfílímù?

Bíbélì pè wọ́n ní àwọn “alágbára ńlá tí wọ́n wà ní ìgbà láéláé, àwọn ọkùnrin olókìkí.” Kí la mọ̀ nípa wọn?

ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ TÓ O LÈ KỌ́ LÁTINÚ BÍBÉLÌ

Nóà Kan Áàkì

Nígbà táwọn áńgẹ́lì burúkú kan fẹ́ àwọn obìnrin tó wà láyé, wọ́n bí àwọn ọmọ tó lágbára, tó sì máa ń fìyà jẹ àwọn èèyàn. Ọ̀pọ̀ èèyàn ló ń hùwà burúkú. Àmọ́ Nóà yátọ̀ torí pé ó nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run, ó sì máa ń ṣègbọràn sí i.