Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìtàn Jónà​—⁠Ẹ̀kọ́ Nípa Ìgboyà àti Àánú

Jèhófà rán wòlíì Jónà pé kó lọ kéde ìdájọ́ sórí ìlú Nínéfè tó jẹ́ olú ìlú Ásíríà, àmọ́ Jónà kọ̀ láti jíṣẹ́ náà; ohun tó ṣẹlẹ̀ tẹ̀ lé e jẹ́ kí Jónà rí ìdí téèyàn fi gbọ́dọ̀ jẹ́ onígboyà àti aláàánú.

O Tún Lè Wo

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

Jónà Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Àwọn Àṣìṣe Rẹ̀

Ǹjẹ́ iṣẹ́ tí Jèhófà ní kó o ṣe ti bà ọ́ lẹ́rù rí bíi ti Jónà? Kí ni ìtàn Jónà kọ́ wa nípa sùúrù àti àánú Jèhófà.

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

Jónà Kọ́ Ìdí Tó Fi Yẹ Kó Jẹ́ Aláàánú

Báwo ni ìtàn Jónà ṣe lè mú ká fara balẹ̀ ṣàyẹ̀wò irú ẹni tá a jẹ́ gan-an?