Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Gbogbo Ẹgbẹ́ Àwọn Ará Wa

Ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún méjì (2,000) ọdún sẹ́yìn, a pàṣẹ fáwọn Kristẹni pé kí wọ́n “máa nífẹ̀ẹ́ gbogbo àwọn ará.” Báwo làwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ń pa àṣẹ yìí mọ́? Fídíò yìí jẹ́ ká rí ọ̀nà mẹ́ta táwọn ará wa kárí ayé ń gbà pa àṣẹ yìí mọ́ nípa: 1) iṣẹ́ ìwáásù, 2) bá a ṣe ń ṣèrànwọ́ nígbà àjálù àti 3) bá a ṣe jọ ń sin Jèhófà Ọlọ́run níṣọ̀kan.

 

O Tún Lè Wo

ÀWỌN ÌṢẸ̀LẸ̀ GIDI

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—A Ṣètò Wa Láti Wàásù Ìhìn Rere

Nílé-lóko làwọn èèyàn ti mọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọ bá a ṣe ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé. Báwo la ṣe ṣètò iṣẹ́ yìí, báwo la ṣe ń darí ẹ̀, báwo la sì ṣe ń rówó ná?