Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?​—Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀

O lè jàǹfààní nínú àwọn ìlànà tó wà nínú fídíò yìí tí o kò bá gbàgbé pé ìyàtọ̀ wà nínú àṣà ìbílẹ̀ kọ̀ọ̀kan tó bá kan ọ̀ràn ìfẹ́rasọ́nà tó máa ń yọrí sí ìgbéyàwó.

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?

Ìlànà Bíbélì lè ràn wá lọ́wọ́ láti yan ọkọ tàbí aya rere, ó sì lè jẹ́ kí tọkọtaya máa fìfẹ́ tòótọ́ hàn sí ara wọn.