JANUARY 30, 2019
OHUN TUNTUN

Bíbélì Àtẹ́tísí​—Ìwé Jémíìsì Ti Wà Lórí Ìkànnì

Bíbélì Àtẹ́tísí​—Ìwé Jémíìsì Ti Wà Lórí Ìkànnì

A ti ka ìwé Jémíìsì sórí ẹ̀rọ látinú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a tún ṣe, ó sì ti wà lórí ìkànnì jw.org.

Tẹ́tí sí ìwé Jémíìsì.