Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2025-2026 Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe
“Máa Jọ́sìn Ní Ẹ̀mí àti Òtítọ́”
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn nǹkan tá a máa gbádùn ní àárọ̀ àti ọ̀sán àpéjọ àyíká tí alábòójútó àyíká máa bá wa ṣe.
Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí bá a ṣe ń bá àpéjọ náà lọ.

