Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ọdún àti Ayẹyẹ

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọdún Kérésìmesì?

Ó máa yà ọ́ lẹ́nu tó o bá ka ìtàn àwọn àṣà Kérésìmesì mẹ́fà táwọn èèyàn mọ̀ dáadáa.

Ìgbà Wo Ni Wọ́n Bí Jésù?

Kà nípa ìdí tí wọ́n fi ń ṣe ọdún Kérésìmesì ní December 25.

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọdún Àjíǹde?

Kà nípa ibi tí àṣà Ọdún Àjíǹde márùn-ún ti wá.

Báwo Ni Ọdún Halloween Ṣe Bẹ̀rẹ̀?

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé látinú ìbọ̀rìṣà ni àwọn ohun tí wọ́n máa ń ṣe nígbà Halloween ti wá, ṣé ó yẹ ká kà á sí?

Kí Ni Ìrékọjá?

Kí ni wọ́n fi ń rántí? Kí nìdí tí Jésù fi ṣe àyọjọ̀ yìí, táwọn Kristẹni lóde òní kò sì ṣe é?