• 240​—Iye àwọn ilẹ̀ tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ń jọ́sìn

  • 8,457,107​—Iye àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

  • 10,071,524​—Iye àwọn èèyàn tí à ń kọ́ ní ẹ̀kọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́

  • 20,175,477​—Iye àwọn tó wá sí Ìrántí Ikú Kristi tí à ń ṣe lọ́dọọdún

  • 120,053​—Iye ìjọ